BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Skip Móríwú and continue reading
Móríwú
Fídíò, Ademola Adeleke àti APC sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí ara wọn lẹ́yìn ìjà òṣèlú tó wáyé l'Osun, Duration 5,47
Fídíò, "Àwọn agbébọn tó ń jà fún ẹ̀sìn gan ń lo òògùn ìbílẹ̀, ṣé ìjọba le fi 1000 Kùránì àti 1m Bíbélì jagun agbébọn báyìí?", Duration 5,36
Fídíò, Ó pẹ́ tí mo ti sá kúrò nílé, mo rán ara mi ní fásitì, ọjọ́ kan làwọn òbí mi rí mi lórí Tẹlifísàn bíi gbajúmọ̀ akọrin - Shodey, Duration 3,47
Fídíò, "Ìdájọ́ ikú tí wọ́n dá fún àwọn tó kọlu ṣọ́ọ̀ṣì Owo kò dá ọmọ mi àti àbúrò mi méjì tí wọ́n pa padà", Duration 3,05
Fídíò, Bí o bá ń pẹ́ kí o tó sùn lálẹ́, ewu ń bẹ fún ìlera ọpọlọ rẹ, Duration 1,27
Fídíò, Bàbá mi ló pàṣẹ fún mi lójú àlá pé kí n máa múra bí ọkùnrin – Funmilayo Elemure Ogunyemi, Duration 4,11
Fídíò, Aráàlú fárígá, ṣèwọ́de ní Ibadan tako ìjọba lórí bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ tí wọ́n jí gbé ṣì ṣe wà ní àhámọ́ , Duration 0,37
Fídíò, Ìfúpá àwọn èèyàn Ayetoro l‘Ondo ń ga sí, torí bí òkun ṣe ń ya wọ ìlú, gbé iléẹ̀kọ́, ilégbèé, iléeṣẹ́, ilẹ̀ àti ibojì òkù lọ, Duration 2,45
Fídíò, Wo àkóbá mọ́kànlá tí ohun mímu ‘Energy Drinks’ le ṣe fún àgọ́ ara rẹ, Duration 1,26
Fídíò, Ìjì òjò líle sí òrúlé, da ògiri wó nílé ẹ̀kọ́ girama ọgbọ̀n l‘Ogbomoso, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ n kẹ́kọ̀ọ́ lábẹ́ ilé àlàpa, Duration 4,32
Fídíò, "Ìjọba rí epo rọ̀bì ní ìlú wa àmọ́ a kò jàǹfààní kankan, kò sí omi, iná, ojú ọ̀nà, ààbò, iléẹ̀kọ́ àti ilé ìwòsàn", Duration 2,16
End of Móríwú
BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ



